Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin

Ọ̀kan pàtàkì tí kò ṣe é fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn lára ẹ̀ka tí lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá pín sí ni orin jẹ́. Bárakú sì ní ọ̀rọ̀ orin láwùjọ ọmọ ènìyàn pàápàá jù lọ àwọn Yorùbá nítorí pé onírúurú ààyè ni orin ti máa ń jẹ jáde nínú ìgbésí-ayé wọn lójoojúmọ́. Bí àwọn akọrin àwùjọ bá sì ń ṣiṣẹ́ ọnà wọn...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Author: Hakeem Olawale
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130101
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
_version_ 1825206071394828288
author Hakeem Olawale
author_facet Hakeem Olawale
author_sort Hakeem Olawale
collection DOAJ
description Ọ̀kan pàtàkì tí kò ṣe é fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn lára ẹ̀ka tí lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá pín sí ni orin jẹ́. Bárakú sì ní ọ̀rọ̀ orin láwùjọ ọmọ ènìyàn pàápàá jù lọ àwọn Yorùbá nítorí pé onírúurú ààyè ni orin ti máa ń jẹ jáde nínú ìgbésí-ayé wọn lójoojúmọ́. Bí àwọn akọrin àwùjọ bá sì ń ṣiṣẹ́ ọnà wọn, ìjìnlẹ̀ èdè tó jinná ni wọ́ n fi máa ń gbé e jáde tí yóò sì máa ṣàfihàn bí irú àwọn akọrin bẹ́ ẹ̀ ṣe gbọ́ èdè àti ìmọ̀ nípa àṣà àwùjọ tó ti ń kọrin nítorí pé ìpohùn ìbílẹ̀ èyí tí orin jẹ́ ọ̀ kan pàtàkì lára wọn dà gẹ́gẹ́ bí àwògbè tàbí díńgí tí a fi ń ríran rí àwùjọ. Ìlò-èdè tó jinná kò sì ṣe é fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn kí àgbékalẹ̀ orin wọ̀nyẹn lè rídìí jòkó dáadáa kí wọ́n sì lè wu etí í gbọ́. Nínú iṣẹ́ yìí, a ṣe àgbéyẹ̀wò àtí àtúpalẹ̀ díẹ̀ lára àwọn ọnà-èdè tó ṣúyọ nínú àṣàyàn orin ìbílẹ̀ Yorùbá Ìlọrin bíi dàdàkúàdà, bàlúù, wákà, kèǹgbè, sẹnwẹlẹ, kàkàkí/bẹ̀ ǹbẹ́ , Orin ọlọ́ mọ-ọba Ìlọrin,orin agbè àti àwọn mìíràn. Lára àwọn ọnà-èdè tí a gbéyẹ̀ wò ni àwítúnwí, àfiwé, ìjẹyọ ẹ̀ ka-èdè, àyálò-èdè àti ipa ‘Creole’ nínú orin ìbílẹ̀ Ìlọrin. Iṣẹ́ yìí ṣàfihàn pé iṣẹ́ ọpọlọ tó jinná ni orin kíkọ àti pé àwọn ọnà-èdè tó máa ń ṣodo sínú wọn lóríṣiríṣi ní iṣẹ́ tí kálukú wọn ń jẹ́ láti túdìí òkodoro nípa àṣà, ìṣe àti èdè àwùjọ tí onírúurú àwọn orin náà ti ń jáde
format Article
id doaj-art-3fe6af696c39472694b922278f1397c9
institution Kabale University
issn 2473-4713
2578-692X
language English
publishDate 2021-12-01
publisher LibraryPress@UF
record_format Article
series Yoruba Studies Review
spelling doaj-art-3fe6af696c39472694b922278f1397c92025-02-07T13:45:01ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2021-12-0161Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin Hakeem Olawale 0Kwara State University, Malete Ọ̀kan pàtàkì tí kò ṣe é fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn lára ẹ̀ka tí lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá pín sí ni orin jẹ́. Bárakú sì ní ọ̀rọ̀ orin láwùjọ ọmọ ènìyàn pàápàá jù lọ àwọn Yorùbá nítorí pé onírúurú ààyè ni orin ti máa ń jẹ jáde nínú ìgbésí-ayé wọn lójoojúmọ́. Bí àwọn akọrin àwùjọ bá sì ń ṣiṣẹ́ ọnà wọn, ìjìnlẹ̀ èdè tó jinná ni wọ́ n fi máa ń gbé e jáde tí yóò sì máa ṣàfihàn bí irú àwọn akọrin bẹ́ ẹ̀ ṣe gbọ́ èdè àti ìmọ̀ nípa àṣà àwùjọ tó ti ń kọrin nítorí pé ìpohùn ìbílẹ̀ èyí tí orin jẹ́ ọ̀ kan pàtàkì lára wọn dà gẹ́gẹ́ bí àwògbè tàbí díńgí tí a fi ń ríran rí àwùjọ. Ìlò-èdè tó jinná kò sì ṣe é fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn kí àgbékalẹ̀ orin wọ̀nyẹn lè rídìí jòkó dáadáa kí wọ́n sì lè wu etí í gbọ́. Nínú iṣẹ́ yìí, a ṣe àgbéyẹ̀wò àtí àtúpalẹ̀ díẹ̀ lára àwọn ọnà-èdè tó ṣúyọ nínú àṣàyàn orin ìbílẹ̀ Yorùbá Ìlọrin bíi dàdàkúàdà, bàlúù, wákà, kèǹgbè, sẹnwẹlẹ, kàkàkí/bẹ̀ ǹbẹ́ , Orin ọlọ́ mọ-ọba Ìlọrin,orin agbè àti àwọn mìíràn. Lára àwọn ọnà-èdè tí a gbéyẹ̀ wò ni àwítúnwí, àfiwé, ìjẹyọ ẹ̀ ka-èdè, àyálò-èdè àti ipa ‘Creole’ nínú orin ìbílẹ̀ Ìlọrin. Iṣẹ́ yìí ṣàfihàn pé iṣẹ́ ọpọlọ tó jinná ni orin kíkọ àti pé àwọn ọnà-èdè tó máa ń ṣodo sínú wọn lóríṣiríṣi ní iṣẹ́ tí kálukú wọn ń jẹ́ láti túdìí òkodoro nípa àṣà, ìṣe àti èdè àwùjọ tí onírúurú àwọn orin náà ti ń jáde https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130101
spellingShingle Hakeem Olawale
Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin
Yoruba Studies Review
title Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin
title_full Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin
title_fullStr Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin
title_full_unstemmed Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin
title_short Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin
title_sort agbeyewo ilo ede ninu orin ibile ilorin
url https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130101
work_keys_str_mv AT hakeemolawale agbeyewoiloedeninuorinibileilorin