Ọjọ́-ọ̀la Èdè Yorùbá ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
Apileko yii pitan ididele eko ede Yoruba ni orile-ede Amerika, o si so olokanojokan awon isoro to n koju awon oluko ati akekoo ede Yoruba ni orile-ede naa, ki o too wa wo sakun ojo-ola eto eko naa nile Amerika. Lara awon aba ti apileko yii gbe kale ki ojo-olo ede Yoruba le dara sii ni: kiko iwe iko...
Saved in:
Main Author: | |
---|---|
Format: | Article |
Language: | English |
Published: |
LibraryPress@UF
2021-12-01
|
Series: | Yoruba Studies Review |
Online Access: | https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130150 |
Tags: |
Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
|
Summary: | Apileko yii pitan ididele eko ede Yoruba ni orile-ede Amerika, o si so olokanojokan awon isoro to n koju awon oluko ati akekoo ede Yoruba ni orile-ede naa, ki o too wa wo sakun ojo-ola eto eko naa nile Amerika. Lara awon aba ti apileko yii gbe kale ki ojo-olo ede Yoruba le dara sii ni: kiko iwe ikoni to ba igba mu, to si see lo pelu imo ero, fifun awon akekoo ni imoran nipa iwulo kiko ede ajoji bi ede akonkunteni, fifi enu ko nipa fonti lati maa fi te Yoruba lori konputa ati odiwon fun ikoni lekoo, titi o fi kan ipese anfani fun awon akekoo lati lo si Naijiria nibi ti awon elede naa ti n lo o ni gbogbo igba.
|
---|---|
ISSN: | 2473-4713 2578-692X |