Ìtúpalẹ̀ Ìjẹwọnúra-àṣà Nínú Àṣàyàn Oríkì Àwọn Ọba Aládé ní Ìjẹ̀bú

Iṣẹ́ yìí gbájú mọ́ ìtúpalẹ̀ àṣàyàn oríkì àwọn ọba aládé ní ilẹ̀ Ìjẹ̀bú. Onírúurú iṣẹ́ ìwádìí ló ti wáyé lórí oríkì àti ipa àwọn ọba aládé láwùjọ Yorùbá, bí ó ti hàn nínú ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ iṣé tí àwọn onímọ̀ ìṣáájú ti ṣe ní ẹka-ìmọ̀ Yorùbá lápapọ̀, ṣùgbọ́n díẹ̀ nínú àwọn onímọ̀ náà ni wọ́n s...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Author: Ayọ̀bámi Mistura Tábí-Àgòrò
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130100
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
_version_ 1825206082508685312
author Ayọ̀bámi Mistura Tábí-Àgòrò
author_facet Ayọ̀bámi Mistura Tábí-Àgòrò
author_sort Ayọ̀bámi Mistura Tábí-Àgòrò
collection DOAJ
description Iṣẹ́ yìí gbájú mọ́ ìtúpalẹ̀ àṣàyàn oríkì àwọn ọba aládé ní ilẹ̀ Ìjẹ̀bú. Onírúurú iṣẹ́ ìwádìí ló ti wáyé lórí oríkì àti ipa àwọn ọba aládé láwùjọ Yorùbá, bí ó ti hàn nínú ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ iṣé tí àwọn onímọ̀ ìṣáájú ti ṣe ní ẹka-ìmọ̀ Yorùbá lápapọ̀, ṣùgbọ́n díẹ̀ nínú àwọn onímọ̀ náà ni wọ́n ṣe iṣẹ́ lórí oríkì àwọn ọba ilẹ̀ Ìjẹ̀bú. Ìwádìí fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé púpọ̀ nínú àwọn ọba ilẹ̀ Ìjẹ̀bú ni wọ́n jẹ́ bọ̀rọ̀kìnní, gẹ́gẹ́ bí ó ti hàn nínú oríkì wọn. Ìwádìí yìí fi àṣàyàn oríkì àwọn ọba aládé ní ilẹ̀ Ìjẹ̀bú hàn gẹ́gẹ́ bí èyí tí àkóónú rẹ̀ kún fún onírúurú ìtàn nípa ètò-ìṣèlú ilẹ̀ Ìjẹ̀bú, ètò-ọrọ̀-ajé àti àṣà tí ó jẹ mọ́ ètò-ìbára-ẹni-gbépọ̀ àwùjọ Ìjẹ̀bú gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà kan tó ní ọlá láwùjọ Yorùbá. Gbogbo àwọn nǹkan tí ìwádìí yìí ṣe àfàyọ rẹ̀ nínú àṣàyàn oríkì àwọn ọba aládé ilè Ìjè ̣ bú ni kò fi bẹ́ẹ̀ fara hàn nínú iṣẹ́ àwọn ̣ onímọ̀ ìṣáájú nípa oríkì ilẹ̀ Ìjẹ̀bú. Iṣẹ́ yìí dí àlàfo náà. Iṣẹ́ yìí fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé oríkì àwọn ọba aládé ilẹ̀ Ìjèbú kún fún ìtàn nípa àwùjọ wọn pẹ̀lú onírúurú àṣà ̣ àti ìṣe àwọn Ìjẹ̀bú. Iṣẹ́ yìí tún fi hàn pé, àkóónú oríkì àwọn ọba aládé ilẹ̀ Ìjẹ̀bú kún fún gbogbo ojúlówó àṣà àti ìṣe àwọn ẹ̀yà náà
format Article
id doaj-art-680202281e27453484aea07637f1a425
institution Kabale University
issn 2473-4713
2578-692X
language English
publishDate 2021-12-01
publisher LibraryPress@UF
record_format Article
series Yoruba Studies Review
spelling doaj-art-680202281e27453484aea07637f1a4252025-02-07T13:45:01ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2021-12-0161Ìtúpalẹ̀ Ìjẹwọnúra-àṣà Nínú Àṣàyàn Oríkì Àwọn Ọba Aládé ní Ìjẹ̀bú Ayọ̀bámi Mistura Tábí-Àgòrò 0Tai Solarin University of Education Iṣẹ́ yìí gbájú mọ́ ìtúpalẹ̀ àṣàyàn oríkì àwọn ọba aládé ní ilẹ̀ Ìjẹ̀bú. Onírúurú iṣẹ́ ìwádìí ló ti wáyé lórí oríkì àti ipa àwọn ọba aládé láwùjọ Yorùbá, bí ó ti hàn nínú ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ iṣé tí àwọn onímọ̀ ìṣáájú ti ṣe ní ẹka-ìmọ̀ Yorùbá lápapọ̀, ṣùgbọ́n díẹ̀ nínú àwọn onímọ̀ náà ni wọ́n ṣe iṣẹ́ lórí oríkì àwọn ọba ilẹ̀ Ìjẹ̀bú. Ìwádìí fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé púpọ̀ nínú àwọn ọba ilẹ̀ Ìjẹ̀bú ni wọ́n jẹ́ bọ̀rọ̀kìnní, gẹ́gẹ́ bí ó ti hàn nínú oríkì wọn. Ìwádìí yìí fi àṣàyàn oríkì àwọn ọba aládé ní ilẹ̀ Ìjẹ̀bú hàn gẹ́gẹ́ bí èyí tí àkóónú rẹ̀ kún fún onírúurú ìtàn nípa ètò-ìṣèlú ilẹ̀ Ìjẹ̀bú, ètò-ọrọ̀-ajé àti àṣà tí ó jẹ mọ́ ètò-ìbára-ẹni-gbépọ̀ àwùjọ Ìjẹ̀bú gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà kan tó ní ọlá láwùjọ Yorùbá. Gbogbo àwọn nǹkan tí ìwádìí yìí ṣe àfàyọ rẹ̀ nínú àṣàyàn oríkì àwọn ọba aládé ilè Ìjè ̣ bú ni kò fi bẹ́ẹ̀ fara hàn nínú iṣẹ́ àwọn ̣ onímọ̀ ìṣáájú nípa oríkì ilẹ̀ Ìjẹ̀bú. Iṣẹ́ yìí dí àlàfo náà. Iṣẹ́ yìí fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé oríkì àwọn ọba aládé ilẹ̀ Ìjèbú kún fún ìtàn nípa àwùjọ wọn pẹ̀lú onírúurú àṣà ̣ àti ìṣe àwọn Ìjẹ̀bú. Iṣẹ́ yìí tún fi hàn pé, àkóónú oríkì àwọn ọba aládé ilẹ̀ Ìjẹ̀bú kún fún gbogbo ojúlówó àṣà àti ìṣe àwọn ẹ̀yà náà https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130100
spellingShingle Ayọ̀bámi Mistura Tábí-Àgòrò
Ìtúpalẹ̀ Ìjẹwọnúra-àṣà Nínú Àṣàyàn Oríkì Àwọn Ọba Aládé ní Ìjẹ̀bú
Yoruba Studies Review
title Ìtúpalẹ̀ Ìjẹwọnúra-àṣà Nínú Àṣàyàn Oríkì Àwọn Ọba Aládé ní Ìjẹ̀bú
title_full Ìtúpalẹ̀ Ìjẹwọnúra-àṣà Nínú Àṣàyàn Oríkì Àwọn Ọba Aládé ní Ìjẹ̀bú
title_fullStr Ìtúpalẹ̀ Ìjẹwọnúra-àṣà Nínú Àṣàyàn Oríkì Àwọn Ọba Aládé ní Ìjẹ̀bú
title_full_unstemmed Ìtúpalẹ̀ Ìjẹwọnúra-àṣà Nínú Àṣàyàn Oríkì Àwọn Ọba Aládé ní Ìjẹ̀bú
title_short Ìtúpalẹ̀ Ìjẹwọnúra-àṣà Nínú Àṣàyàn Oríkì Àwọn Ọba Aládé ní Ìjẹ̀bú
title_sort itupale ijewonura asa ninu asayan oriki awon oba alade ni ijebu
url https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130100
work_keys_str_mv AT ayobamimisturatabiagoro itupaleijewonuraasaninuasayanorikiawonobaaladeniijebu