Àrífàyọ Ìmọ̀ Abínibí nínú Oríkì Orílẹ̀ Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n tí Adébóyè Babalọlá kọ

Akiyesi pe opo onimo ni won ti sise lori oriki orile. Awon kan fi oju tiori imo ibagbepo awujo, imo isewadii-fininin-isedaniyam (anthropological method), ifoju-aato-wo, ifoju-ihun-wo, amo ko si eni to ti i lo tiori imo abinibi (indigenous knowledge) lati yiri oriki orile wo. Eredie ree ti a wa fi l...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Authors: Duro Adeleke, Adeola Mobolaji
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130152
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
Description
Summary:Akiyesi pe opo onimo ni won ti sise lori oriki orile. Awon kan fi oju tiori imo ibagbepo awujo, imo isewadii-fininin-isedaniyam (anthropological method), ifoju-aato-wo, ifoju-ihun-wo, amo ko si eni to ti i lo tiori imo abinibi (indigenous knowledge) lati yiri oriki orile wo. Eredie ree ti a wa fi lo tiori imo abinibi lati wo bi awon Yoruba se n samulo awon nnkan ti o wa larowoto ati ayika won. Agbalo agbabo ni pe a ri eri pe opo imo ibile lo je yo ti o si hande ninu oriki orile, paapaa awon eyi ti ijoba ile Naijiria i ba fi pese ise fun ogoro odo ti won fese gba igboro kiri. Lara imo abinibi ti a ri naa ni ise ona sise, ile kiko lona ibile, aso hibun ati ise tewe-tegbo. 
ISSN:2473-4713
2578-692X