Àrífàyọ Ìmọ̀ Abínibí nínú Oríkì Orílẹ̀ Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n tí Adébóyè Babalọlá kọ

Akiyesi pe opo onimo ni won ti sise lori oriki orile. Awon kan fi oju tiori imo ibagbepo awujo, imo isewadii-fininin-isedaniyam (anthropological method), ifoju-aato-wo, ifoju-ihun-wo, amo ko si eni to ti i lo tiori imo abinibi (indigenous knowledge) lati yiri oriki orile wo. Eredie ree ti a wa fi l...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Authors: Duro Adeleke, Adeola Mobolaji
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130152
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
_version_ 1825206089262563328
author Duro Adeleke
Adeola Mobolaji
author_facet Duro Adeleke
Adeola Mobolaji
author_sort Duro Adeleke
collection DOAJ
description Akiyesi pe opo onimo ni won ti sise lori oriki orile. Awon kan fi oju tiori imo ibagbepo awujo, imo isewadii-fininin-isedaniyam (anthropological method), ifoju-aato-wo, ifoju-ihun-wo, amo ko si eni to ti i lo tiori imo abinibi (indigenous knowledge) lati yiri oriki orile wo. Eredie ree ti a wa fi lo tiori imo abinibi lati wo bi awon Yoruba se n samulo awon nnkan ti o wa larowoto ati ayika won. Agbalo agbabo ni pe a ri eri pe opo imo ibile lo je yo ti o si hande ninu oriki orile, paapaa awon eyi ti ijoba ile Naijiria i ba fi pese ise fun ogoro odo ti won fese gba igboro kiri. Lara imo abinibi ti a ri naa ni ise ona sise, ile kiko lona ibile, aso hibun ati ise tewe-tegbo. 
format Article
id doaj-art-7ef2dccb44bb45489845489f65265f77
institution Kabale University
issn 2473-4713
2578-692X
language English
publishDate 2021-12-01
publisher LibraryPress@UF
record_format Article
series Yoruba Studies Review
spelling doaj-art-7ef2dccb44bb45489845489f65265f772025-02-07T13:44:40ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2021-12-0112Àrífàyọ Ìmọ̀ Abínibí nínú Oríkì Orílẹ̀ Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n tí Adébóyè Babalọlá kọDuro Adeleke0Adeola Mobolaji1University of IbadanEmmanuel Alayande College of Education Akiyesi pe opo onimo ni won ti sise lori oriki orile. Awon kan fi oju tiori imo ibagbepo awujo, imo isewadii-fininin-isedaniyam (anthropological method), ifoju-aato-wo, ifoju-ihun-wo, amo ko si eni to ti i lo tiori imo abinibi (indigenous knowledge) lati yiri oriki orile wo. Eredie ree ti a wa fi lo tiori imo abinibi lati wo bi awon Yoruba se n samulo awon nnkan ti o wa larowoto ati ayika won. Agbalo agbabo ni pe a ri eri pe opo imo ibile lo je yo ti o si hande ninu oriki orile, paapaa awon eyi ti ijoba ile Naijiria i ba fi pese ise fun ogoro odo ti won fese gba igboro kiri. Lara imo abinibi ti a ri naa ni ise ona sise, ile kiko lona ibile, aso hibun ati ise tewe-tegbo.  https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130152
spellingShingle Duro Adeleke
Adeola Mobolaji
Àrífàyọ Ìmọ̀ Abínibí nínú Oríkì Orílẹ̀ Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n tí Adébóyè Babalọlá kọ
Yoruba Studies Review
title Àrífàyọ Ìmọ̀ Abínibí nínú Oríkì Orílẹ̀ Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n tí Adébóyè Babalọlá kọ
title_full Àrífàyọ Ìmọ̀ Abínibí nínú Oríkì Orílẹ̀ Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n tí Adébóyè Babalọlá kọ
title_fullStr Àrífàyọ Ìmọ̀ Abínibí nínú Oríkì Orílẹ̀ Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n tí Adébóyè Babalọlá kọ
title_full_unstemmed Àrífàyọ Ìmọ̀ Abínibí nínú Oríkì Orílẹ̀ Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n tí Adébóyè Babalọlá kọ
title_short Àrífàyọ Ìmọ̀ Abínibí nínú Oríkì Orílẹ̀ Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n tí Adébóyè Babalọlá kọ
title_sort arifayo imo abinibi ninu oriki orile metadinlogbon ti adeboye babalola ko
url https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130152
work_keys_str_mv AT duroadeleke arifayoimoabinibininuorikiorilemetadinlogbontiadeboyebabalolako
AT adeolamobolaji arifayoimoabinibininuorikiorilemetadinlogbontiadeboyebabalolako