Ìlò Èébú Nínú Àwọn Ìtàn-àròsọ Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ Òkédìjí

Ògúnṣínà (1992), Adébọ̀wálé (1994) àti Ìṣọ̀lá (1995) ti ṣe àlàyé lórí ìlò èdè Òkédìjí nínú ìtàn-àròsọ Àjà Ló Lẹrù, Àgbàlagbà Akàn àti Ká Rìn Ká Pọ̀ ṣùgbọ́n kò sí lámèyítọ́ tó yẹ ìlò èébú wò nínú àwọn ìwé náà tàbí ti òǹkọ̀ wé ìtàn-àròsọ Yorùbá mìíràn. Iṣẹ́ yìí ṣe àyẹ̀ wò ìlò èébú nínú ìtàn-àròsọ Òk...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Authors: Olúyẹmisí Adébọ̀wálé, Tèmítọ́pẹ́ Olúmúyìwá
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130088
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
_version_ 1825206019578396672
author Olúyẹmisí Adébọ̀wálé
Tèmítọ́pẹ́ Olúmúyìwá
author_facet Olúyẹmisí Adébọ̀wálé
Tèmítọ́pẹ́ Olúmúyìwá
author_sort Olúyẹmisí Adébọ̀wálé
collection DOAJ
description Ògúnṣínà (1992), Adébọ̀wálé (1994) àti Ìṣọ̀lá (1995) ti ṣe àlàyé lórí ìlò èdè Òkédìjí nínú ìtàn-àròsọ Àjà Ló Lẹrù, Àgbàlagbà Akàn àti Ká Rìn Ká Pọ̀ ṣùgbọ́n kò sí lámèyítọ́ tó yẹ ìlò èébú wò nínú àwọn ìwé náà tàbí ti òǹkọ̀ wé ìtàn-àròsọ Yorùbá mìíràn. Iṣẹ́ yìí ṣe àyẹ̀ wò ìlò èébú nínú ìtàn-àròsọ Òkédìjí, ó sì lo ọgbọ́ n ìwádìí kíka àwọn ìwé náà ní àkàtúnkà láti ṣe àfàyọ àti àkójọpọ̀ gbogbo èébú tó súyọ kí a tó ṣe ìtúpalẹ̀ wọn. Tíọ́rì ọ̀nà ìṣafọ̀ tó jẹmọ́ èròǹgbà aṣafọ̀ àti ìmọ̀lára òsùnsùn-afọ̀ nípa afọ̀ la fi ṣe àlàyé wa. Ìgbà ọ̀ọ́dúnrún àti ọ̀kandínláàádọ́rùn-ún ni Òkédìjí ti lo èébú nínú àwọn ìtàn-àròsọ rẹ̀, ọ̀nà ìṣafọ̀ méjì tó gbà ṣe àgbékalẹ̀ èébú ni ìṣafọ̀ sínú àti ìṣafọ̀ síta. Ìsọ̀ rí èébú wọ̀ nyí lè jẹ́ èébú ti ẹlẹ́ yọ-ọ̀ rọ̀ , alápòólà, odindi gbólóhùn, oníbéèrè, òwe àti oríkì ajẹméèébú. Iṣẹ́ tí àwọn aṣafọ̀ fi èébú ṣe nínú ìsọ̀ rọ̀ gbèsì la fi kásẹ̀ àlàyé wa.
format Article
id doaj-art-9029ac6d7cfc4e0eb3a7c6fd637bf7ce
institution Kabale University
issn 2473-4713
2578-692X
language English
publishDate 2021-12-01
publisher LibraryPress@UF
record_format Article
series Yoruba Studies Review
spelling doaj-art-9029ac6d7cfc4e0eb3a7c6fd637bf7ce2025-02-07T13:45:07ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2021-12-0161Ìlò Èébú Nínú Àwọn Ìtàn-àròsọ Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ Òkédìjí Olúyẹmisí Adébọ̀wálé0Tèmítọ́pẹ́ Olúmúyìwá 1Adékúnlé Ajáṣin UniversityAdékúnlé Ajáṣin University Ògúnṣínà (1992), Adébọ̀wálé (1994) àti Ìṣọ̀lá (1995) ti ṣe àlàyé lórí ìlò èdè Òkédìjí nínú ìtàn-àròsọ Àjà Ló Lẹrù, Àgbàlagbà Akàn àti Ká Rìn Ká Pọ̀ ṣùgbọ́n kò sí lámèyítọ́ tó yẹ ìlò èébú wò nínú àwọn ìwé náà tàbí ti òǹkọ̀ wé ìtàn-àròsọ Yorùbá mìíràn. Iṣẹ́ yìí ṣe àyẹ̀ wò ìlò èébú nínú ìtàn-àròsọ Òkédìjí, ó sì lo ọgbọ́ n ìwádìí kíka àwọn ìwé náà ní àkàtúnkà láti ṣe àfàyọ àti àkójọpọ̀ gbogbo èébú tó súyọ kí a tó ṣe ìtúpalẹ̀ wọn. Tíọ́rì ọ̀nà ìṣafọ̀ tó jẹmọ́ èròǹgbà aṣafọ̀ àti ìmọ̀lára òsùnsùn-afọ̀ nípa afọ̀ la fi ṣe àlàyé wa. Ìgbà ọ̀ọ́dúnrún àti ọ̀kandínláàádọ́rùn-ún ni Òkédìjí ti lo èébú nínú àwọn ìtàn-àròsọ rẹ̀, ọ̀nà ìṣafọ̀ méjì tó gbà ṣe àgbékalẹ̀ èébú ni ìṣafọ̀ sínú àti ìṣafọ̀ síta. Ìsọ̀ rí èébú wọ̀ nyí lè jẹ́ èébú ti ẹlẹ́ yọ-ọ̀ rọ̀ , alápòólà, odindi gbólóhùn, oníbéèrè, òwe àti oríkì ajẹméèébú. Iṣẹ́ tí àwọn aṣafọ̀ fi èébú ṣe nínú ìsọ̀ rọ̀ gbèsì la fi kásẹ̀ àlàyé wa. https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130088
spellingShingle Olúyẹmisí Adébọ̀wálé
Tèmítọ́pẹ́ Olúmúyìwá
Ìlò Èébú Nínú Àwọn Ìtàn-àròsọ Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ Òkédìjí
Yoruba Studies Review
title Ìlò Èébú Nínú Àwọn Ìtàn-àròsọ Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ Òkédìjí
title_full Ìlò Èébú Nínú Àwọn Ìtàn-àròsọ Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ Òkédìjí
title_fullStr Ìlò Èébú Nínú Àwọn Ìtàn-àròsọ Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ Òkédìjí
title_full_unstemmed Ìlò Èébú Nínú Àwọn Ìtàn-àròsọ Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ Òkédìjí
title_short Ìlò Èébú Nínú Àwọn Ìtàn-àròsọ Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ Òkédìjí
title_sort ilo eebu ninu awon itan aroso otelemuye okediji
url https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130088
work_keys_str_mv AT oluyemisiadebowale iloeebuninuawonitanarosootelemuyeokediji
AT temitopeolumuyiwa iloeebuninuawonitanarosootelemuyeokediji