Ìlò Èébú Nínú Àwọn Ìtàn-àròsọ Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ Òkédìjí
Ògúnṣínà (1992), Adébọ̀wálé (1994) àti Ìṣọ̀lá (1995) ti ṣe àlàyé lórí ìlò èdè Òkédìjí nínú ìtàn-àròsọ Àjà Ló Lẹrù, Àgbàlagbà Akàn àti Ká Rìn Ká Pọ̀ ṣùgbọ́n kò sí lámèyítọ́ tó yẹ ìlò èébú wò nínú àwọn ìwé náà tàbí ti òǹkọ̀ wé ìtàn-àròsọ Yorùbá mìíràn. Iṣẹ́ yìí ṣe àyẹ̀ wò ìlò èébú nínú ìtàn-àròsọ Òk...
Saved in:
Main Authors: | Olúyẹmisí Adébọ̀wálé, Tèmítọ́pẹ́ Olúmúyìwá |
---|---|
Format: | Article |
Language: | English |
Published: |
LibraryPress@UF
2021-12-01
|
Series: | Yoruba Studies Review |
Online Access: | https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130088 |
Tags: |
Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
|
Similar Items
-
Ìfarajọ-Èébú nínú Àwọn Àsàyàn Oríkì Yorùbá
by: Abídèmi. O. Bọlárìnwá
Published: (2021-12-01) -
Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin
by: Hakeem Olawale
Published: (2021-12-01) -
Àkànlò-èdè Tuntun Nínú Àwọn Orin Ọ ̀ dọ ́ Ìwòyí
by: Dayo Akanmu
Published: (2021-12-01) -
Àgbéyẹ̀wò Ipa Èdè, Àṣà, àti Lítíréṣọ̀ Yorùbá Nínú ọ̀gbagadè Ìtàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
by: Arinpe Adejumo
Published: (2021-12-01) -
Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló Lẹrù
by: Folúkẹ Bọláńlé Adékẹ̀yè, et al.
Published: (2021-12-01)