̀ ̀ 'Itànkále̩ ̀ Èrò E̩ ni nínú Às̩ àyàn Fíìmù Yorùbá

 Ìtànkálẹ̀ èrò ẹni tí ọ̀ pọ̀ lọpọ̀ omímọ̀ gbà bí èrò òdì ìpọ́ nrọ́ léwé tàbí irọ́ nípa tó lóòrìn láwùjọ, bákan náà, ni ó sì jẹ́ ohun èlò pàtàkì nínú ìgbékalẹ̀ fíímù Yorùbá. Is̩ é ̩ ìwádìí lórí ìtànkálè ̩ èrò e̩ ni àti ìbás̩ epò̩ rè ̩ pè ̩ lú ìs̩ e-o̩ kàn kò tí ì pò̩ tó ni...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Author: Olúbùnmi Tèmítọ́pẹ́Adú
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130092
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
_version_ 1825206037387411456
author Olúbùnmi Tèmítọ́pẹ́Adú
author_facet Olúbùnmi Tèmítọ́pẹ́Adú
author_sort Olúbùnmi Tèmítọ́pẹ́Adú
collection DOAJ
description  Ìtànkálẹ̀ èrò ẹni tí ọ̀ pọ̀ lọpọ̀ omímọ̀ gbà bí èrò òdì ìpọ́ nrọ́ léwé tàbí irọ́ nípa tó lóòrìn láwùjọ, bákan náà, ni ó sì jẹ́ ohun èlò pàtàkì nínú ìgbékalẹ̀ fíímù Yorùbá. Is̩ é ̩ ìwádìí lórí ìtànkálè ̩ èrò e̩ ni àti ìbás̩ epò̩ rè ̩ pè ̩ lú ìs̩ e-o̩ kàn kò tí ì pò̩ tó nínú fíìmù Yorùbá, èyí ni is̩ é ̩ yìí tànmó̩ lè ̩ sí. Tíó̩ rì aje̩ mó̩ s̩ e-o̩ kàn tó dá lórí ìko̩ lura ninú o̩ po̩ lo̩ àti ìs̩ àkóso rè ̩ ni a lò, èyí tó s̩ àfihàn wíwá ìtumò̩ ìjìnlè ̩ sí ìhùwàsí ènìyàn. A s̩ àmúlò fíìmù méje kan tí a mò̩ -o̩ ́ n-mò̩ s̩ àyàn fún ìtúpalè ̩ nítorí wó̩ n kún fó̩ fó̩ fún kókó tí is̩ é ̩ yìí dá lé. A wo àwo̩ n fíìmù yìí, a sì s̩ e àdàko̩ àti ìtúpalè ̩ wo̩ n fínnífinní. Ìtànkálè ̩ èrò e̩ ni farahàn nínú ètò ìs̩ èlú/is̩ è- jo̩ ba, è ̩sìn, ìlàsílè ̩ às̩ à àti nínú orúko̩ ìyàsó̩ tò̩ /ìfè ̩ gànpeni. Àbùdá àdámó̩ , ìlera o̩ po̩ lo̩ , ìrírí ìgbà èwe àti ìhùwàsí aje̩mó̩ s̩ e-o̩ kàn a máa nípa lórí às̩ eyo̩ rí tàbí ì- jákulè ̩ ìtànkálè ̩ èrò e̩ ni.
format Article
id doaj-art-d22f447634e4425aa9c57d1c8b51e3a2
institution Kabale University
issn 2473-4713
2578-692X
language English
publishDate 2021-12-01
publisher LibraryPress@UF
record_format Article
series Yoruba Studies Review
spelling doaj-art-d22f447634e4425aa9c57d1c8b51e3a22025-02-07T13:45:05ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2021-12-0161̀ ̀ 'Itànkále̩ ̀ Èrò E̩ ni nínú Às̩ àyàn Fíìmù Yorùbá Olúbùnmi Tèmítọ́pẹ́Adú0Federal College of Education, Abe̩òkúta  Ìtànkálẹ̀ èrò ẹni tí ọ̀ pọ̀ lọpọ̀ omímọ̀ gbà bí èrò òdì ìpọ́ nrọ́ léwé tàbí irọ́ nípa tó lóòrìn láwùjọ, bákan náà, ni ó sì jẹ́ ohun èlò pàtàkì nínú ìgbékalẹ̀ fíímù Yorùbá. Is̩ é ̩ ìwádìí lórí ìtànkálè ̩ èrò e̩ ni àti ìbás̩ epò̩ rè ̩ pè ̩ lú ìs̩ e-o̩ kàn kò tí ì pò̩ tó nínú fíìmù Yorùbá, èyí ni is̩ é ̩ yìí tànmó̩ lè ̩ sí. Tíó̩ rì aje̩ mó̩ s̩ e-o̩ kàn tó dá lórí ìko̩ lura ninú o̩ po̩ lo̩ àti ìs̩ àkóso rè ̩ ni a lò, èyí tó s̩ àfihàn wíwá ìtumò̩ ìjìnlè ̩ sí ìhùwàsí ènìyàn. A s̩ àmúlò fíìmù méje kan tí a mò̩ -o̩ ́ n-mò̩ s̩ àyàn fún ìtúpalè ̩ nítorí wó̩ n kún fó̩ fó̩ fún kókó tí is̩ é ̩ yìí dá lé. A wo àwo̩ n fíìmù yìí, a sì s̩ e àdàko̩ àti ìtúpalè ̩ wo̩ n fínnífinní. Ìtànkálè ̩ èrò e̩ ni farahàn nínú ètò ìs̩ èlú/is̩ è- jo̩ ba, è ̩sìn, ìlàsílè ̩ às̩ à àti nínú orúko̩ ìyàsó̩ tò̩ /ìfè ̩ gànpeni. Àbùdá àdámó̩ , ìlera o̩ po̩ lo̩ , ìrírí ìgbà èwe àti ìhùwàsí aje̩mó̩ s̩ e-o̩ kàn a máa nípa lórí às̩ eyo̩ rí tàbí ì- jákulè ̩ ìtànkálè ̩ èrò e̩ ni. https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130092
spellingShingle Olúbùnmi Tèmítọ́pẹ́Adú
̀ ̀ 'Itànkále̩ ̀ Èrò E̩ ni nínú Às̩ àyàn Fíìmù Yorùbá
Yoruba Studies Review
title ̀ ̀ 'Itànkále̩ ̀ Èrò E̩ ni nínú Às̩ àyàn Fíìmù Yorùbá
title_full ̀ ̀ 'Itànkále̩ ̀ Èrò E̩ ni nínú Às̩ àyàn Fíìmù Yorùbá
title_fullStr ̀ ̀ 'Itànkále̩ ̀ Èrò E̩ ni nínú Às̩ àyàn Fíìmù Yorùbá
title_full_unstemmed ̀ ̀ 'Itànkále̩ ̀ Èrò E̩ ni nínú Às̩ àyàn Fíìmù Yorùbá
title_short ̀ ̀ 'Itànkále̩ ̀ Èrò E̩ ni nínú Às̩ àyàn Fíìmù Yorùbá
title_sort ̀ ̀ itankale ̀ ero e ni ninu as ayan fiimu yoruba
url https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130092
work_keys_str_mv AT olubunmitemitopeadu itankaleeroenininuasayanfiimuyoruba