Igi Ńlá Wó: Ọlábìyí, Èèyàn Iyì Tí n Jẹ́ Yáì Sùn Kalẹ̀ Gbalaja!
“Ọkùnrin lọ! Ọkùnrin lọ! Ò-bọ Sòkòtò f’ẹnu è sọlè ̣ ;̣ Ọkùnrin lọọọ!” Igi dá nígbó; Gbogbo igbó pa késekése! Àgbà Òjọ̀ gbó ̣ n dolóògbé; ̣ Ilé ìmò dìtàn poo! ̣ Gbogbo àgbáyé ń ṣòfọ̀ ọmọ Odùduwà tó sílè ̣ wò ̣ !̣ Bíkú bá pa’jú ẹni dé, Ẹgbé ẹni a sì...
Saved in:
Main Author: | |
---|---|
Format: | Article |
Language: | English |
Published: |
LibraryPress@UF
2021-12-01
|
Series: | Yoruba Studies Review |
Online Access: | https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130108 |
Tags: |
Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
|
Summary: | “Ọkùnrin lọ!
Ọkùnrin lọ!
Ò-bọ Sòkòtò f’ẹnu è sọlè ̣ ;̣
Ọkùnrin lọọọ!”
Igi dá nígbó;
Gbogbo igbó pa késekése!
Àgbà Òjọ̀ gbó ̣ n dolóògbé; ̣
Ilé ìmò dìtàn poo! ̣
Gbogbo àgbáyé ń ṣòfọ̀ ọmọ Odùduwà tó sílè ̣ wò ̣ !̣
Bíkú bá pa’jú ẹni dé,
Ẹgbé ẹni a sì máa wá rìrì kiri! ̣
Àwọn èèyàn tó màṣà tó mèdè, tó mẹni màṣà mèdè,
Gbogbo wọn ń dárò ẹni ire tó lọ!
Bí a bá pe’rí akọni,
À sì fidá lalè!̣
Àgbà ńlá ló fó!̣
Kete omi ta gbé rodò, kómi ó lè wálé subú yékẹ́ ,̣
Kasán já;
Agbagbáṣo kò rígbà ṣo o!
Ìlú Ṣábèẹ́ àt’orílè ̣ -èdè Bìnì nìkan kó ̣ ló pàdánù ẹni ire tó lọ; ̣
Gbogbo ayé ló ń mímí èdùn ló ̣ kàn nítòsí àti lókèèrè réré! ̣
Ibi téégún ṣeré dé,
Gbogbo wọn ni ò lè réégún mó!̣
Èkú nìkan ni gbogbo wa ń wò nílè ̣ !̣
Ẹyẹ sí, Ẹ
yẹ lọ;
Ìyé nìkan ló kù táaráyé ó máa wò l’é ̣ yìn ẹyẹ! ̣
A-gbéni-rìnrìn-àjò-dé’bi- ó sunwòn ti té ̣ rí gbaṣọ!
|
---|---|
ISSN: | 2473-4713 2578-692X |