Igi Ńlá Wó: Ọlábìyí, Èèyàn Iyì Tí n Jẹ́ Yáì Sùn Kalẹ̀ Gbalaja!

“Ọkùnrin lọ!  Ọkùnrin lọ!  Ò-bọ Sòkòtò f’ẹnu è sọlè ̣ ;̣ Ọkùnrin lọọọ!” Igi dá nígbó; Gbogbo igbó pa késekése! Àgbà Òjọ̀ gbó ̣ n dolóògbé; ̣  Ilé ìmò dìtàn poo! ̣ Gbogbo àgbáyé ń ṣòfọ̀ ọmọ Odùduwà tó sílè ̣ wò ̣ !̣ Bíkú bá pa’jú ẹni dé,  Ẹgbé ẹni a sì...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Author: Báyọ̀ Ọmọlọlá
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130108
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
_version_ 1825206116761468928
author Báyọ̀ Ọmọlọlá
author_facet Báyọ̀ Ọmọlọlá
author_sort Báyọ̀ Ọmọlọlá
collection DOAJ
description “Ọkùnrin lọ!  Ọkùnrin lọ!  Ò-bọ Sòkòtò f’ẹnu è sọlè ̣ ;̣ Ọkùnrin lọọọ!” Igi dá nígbó; Gbogbo igbó pa késekése! Àgbà Òjọ̀ gbó ̣ n dolóògbé; ̣  Ilé ìmò dìtàn poo! ̣ Gbogbo àgbáyé ń ṣòfọ̀ ọmọ Odùduwà tó sílè ̣ wò ̣ !̣ Bíkú bá pa’jú ẹni dé,  Ẹgbé ẹni a sì máa wá rìrì kiri! ̣ Àwọn èèyàn tó màṣà tó mèdè, tó mẹni màṣà mèdè, Gbogbo wọn ń dárò ẹni ire tó lọ! Bí a bá pe’rí akọni,  À sì fidá lalè!̣ Àgbà ńlá ló fó!̣ Kete omi ta gbé rodò, kómi ó lè wálé subú yékẹ́ ,̣ Kasán já; Agbagbáṣo kò rígbà ṣo o! Ìlú Ṣábèẹ́ àt’orílè ̣ -èdè Bìnì nìkan kó ̣ ló pàdánù ẹni ire tó lọ; ̣ Gbogbo ayé ló ń mímí èdùn ló ̣ kàn nítòsí àti lókèèrè réré! ̣ Ibi téégún ṣeré dé,  Gbogbo wọn ni ò lè réégún mó!̣ Èkú nìkan ni gbogbo wa ń wò nílè ̣ !̣ Ẹyẹ sí, Ẹ yẹ lọ; Ìyé nìkan ló kù táaráyé ó máa wò l’é ̣ yìn ẹyẹ! ̣  A-gbéni-rìnrìn-àjò-dé’bi- ó sunwòn ti té ̣ rí gbaṣọ!    
format Article
id doaj-art-da2ef2009ea0422297ff64f0decebb1f
institution Kabale University
issn 2473-4713
2578-692X
language English
publishDate 2021-12-01
publisher LibraryPress@UF
record_format Article
series Yoruba Studies Review
spelling doaj-art-da2ef2009ea0422297ff64f0decebb1f2025-02-07T13:44:54ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2021-12-0161Igi Ńlá Wó: Ọlábìyí, Èèyàn Iyì Tí n Jẹ́ Yáì Sùn Kalẹ̀ Gbalaja! Báyọ̀ Ọmọlọlá 0Howard University “Ọkùnrin lọ!  Ọkùnrin lọ!  Ò-bọ Sòkòtò f’ẹnu è sọlè ̣ ;̣ Ọkùnrin lọọọ!” Igi dá nígbó; Gbogbo igbó pa késekése! Àgbà Òjọ̀ gbó ̣ n dolóògbé; ̣  Ilé ìmò dìtàn poo! ̣ Gbogbo àgbáyé ń ṣòfọ̀ ọmọ Odùduwà tó sílè ̣ wò ̣ !̣ Bíkú bá pa’jú ẹni dé,  Ẹgbé ẹni a sì máa wá rìrì kiri! ̣ Àwọn èèyàn tó màṣà tó mèdè, tó mẹni màṣà mèdè, Gbogbo wọn ń dárò ẹni ire tó lọ! Bí a bá pe’rí akọni,  À sì fidá lalè!̣ Àgbà ńlá ló fó!̣ Kete omi ta gbé rodò, kómi ó lè wálé subú yékẹ́ ,̣ Kasán já; Agbagbáṣo kò rígbà ṣo o! Ìlú Ṣábèẹ́ àt’orílè ̣ -èdè Bìnì nìkan kó ̣ ló pàdánù ẹni ire tó lọ; ̣ Gbogbo ayé ló ń mímí èdùn ló ̣ kàn nítòsí àti lókèèrè réré! ̣ Ibi téégún ṣeré dé,  Gbogbo wọn ni ò lè réégún mó!̣ Èkú nìkan ni gbogbo wa ń wò nílè ̣ !̣ Ẹyẹ sí, Ẹ yẹ lọ; Ìyé nìkan ló kù táaráyé ó máa wò l’é ̣ yìn ẹyẹ! ̣  A-gbéni-rìnrìn-àjò-dé’bi- ó sunwòn ti té ̣ rí gbaṣọ!     https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130108
spellingShingle Báyọ̀ Ọmọlọlá
Igi Ńlá Wó: Ọlábìyí, Èèyàn Iyì Tí n Jẹ́ Yáì Sùn Kalẹ̀ Gbalaja!
Yoruba Studies Review
title Igi Ńlá Wó: Ọlábìyí, Èèyàn Iyì Tí n Jẹ́ Yáì Sùn Kalẹ̀ Gbalaja!
title_full Igi Ńlá Wó: Ọlábìyí, Èèyàn Iyì Tí n Jẹ́ Yáì Sùn Kalẹ̀ Gbalaja!
title_fullStr Igi Ńlá Wó: Ọlábìyí, Èèyàn Iyì Tí n Jẹ́ Yáì Sùn Kalẹ̀ Gbalaja!
title_full_unstemmed Igi Ńlá Wó: Ọlábìyí, Èèyàn Iyì Tí n Jẹ́ Yáì Sùn Kalẹ̀ Gbalaja!
title_short Igi Ńlá Wó: Ọlábìyí, Èèyàn Iyì Tí n Jẹ́ Yáì Sùn Kalẹ̀ Gbalaja!
title_sort igi nla wo olabiyi eeyan iyi ti n je yai sun kale gbalaja
url https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130108
work_keys_str_mv AT bayoomolola iginlawoolabiyieeyaniyitinjeyaisunkalegbalaja