Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì”

Digital Nollywood jẹ́ iṣé ìwádìí dígítà tí ó bẹ̀ rẹ̀ ní 2018 láti ṣe àgbékalè ìtàn fíìmù ní Nàìjíríà. Ìlànà ìwádìí yìí ń ṣe àmúlò àwọn ohun àfojúrí àti àwọn ìwé àlẹ̀ móde tí wọ́ n fi ṣe ìpolówó àwọn fíìmù, pàápàá jù lọ ní ikọ̀ fíìmù tí a mọ̀ sí Nollywood. Fún iṣẹ́ Digital Nollywood, a rí àwọn ohun...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Author: ‘Gbenga Adeoba
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2023-05-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/134097
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
_version_ 1825206120147320832
author ‘Gbenga Adeoba
author_facet ‘Gbenga Adeoba
author_sort ‘Gbenga Adeoba
collection DOAJ
description Digital Nollywood jẹ́ iṣé ìwádìí dígítà tí ó bẹ̀ rẹ̀ ní 2018 láti ṣe àgbékalè ìtàn fíìmù ní Nàìjíríà. Ìlànà ìwádìí yìí ń ṣe àmúlò àwọn ohun àfojúrí àti àwọn ìwé àlẹ̀ móde tí wọ́ n fi ṣe ìpolówó àwọn fíìmù, pàápàá jù lọ ní ikọ̀ fíìmù tí a mọ̀ sí Nollywood. Fún iṣẹ́ Digital Nollywood, a rí àwọn ohun èlò àfojúrí àti ìwé àlẹ̀ móde wọ̀ nyí gẹ́ gẹ́ bíi iṣẹ́ ọnà tí ó wúlò fún ìṣèwádìí iṣẹ́ ìtàn Nollywood ní ọ̀ nà tí ó yàtò. Ní oríṣiríṣi ọ̀ nà, iṣẹ́ yìí ń lo àwọn ìwé àlẹ̀ móde wọ̀ nyí láti ṣe àgbékalè ìtàn àwọn ohun ìkéde tí ó ṣe àmúlò àwọn nǹkan tí ó jé tiwantiwa. Ní ìtají sí bí àwọn ohun èlò àfojúrí àti ìwé àlẹ̀ móde wọ̀ nyí ti ṣe ń di àwátì, iṣẹ́ yìí ń ṣe àmúlò àwọn ìtẹ̀ síwájú tí ó pemọ́ ìmọ̀ ẹ̀ rọ láti wo àwọn ọ̀ nà míràn tí a lè gbà se iṣẹ́ ìwádìí ìtàn tàbí se àgbéyèwò àṣà àti ìṣe ní ilè Africa. Nípasẹ̀ àmúlò ohun àgbéjáde ayélujára, Digital Nollywood ní èrò láti di iṣẹ́ ìwádìí dígítà tí ó ń ṣe ìdásí àti ìtẹ́ pẹpẹ ìwé àlẹ̀ móde àwọn fíìmù Nollywood nípasẹ̀ àgbàjọ àwọn ìwé wọ̀ nyí ní orí pẹpẹ Omeka.  
format Article
id doaj-art-e50ac2613f084b66804416456f1bfe2e
institution Kabale University
issn 2473-4713
2578-692X
language English
publishDate 2023-05-01
publisher LibraryPress@UF
record_format Article
series Yoruba Studies Review
spelling doaj-art-e50ac2613f084b66804416456f1bfe2e2025-02-07T13:44:11ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2023-05-0181 Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìg씑Gbenga Adeoba0Washington University in St. Louis Digital Nollywood jẹ́ iṣé ìwádìí dígítà tí ó bẹ̀ rẹ̀ ní 2018 láti ṣe àgbékalè ìtàn fíìmù ní Nàìjíríà. Ìlànà ìwádìí yìí ń ṣe àmúlò àwọn ohun àfojúrí àti àwọn ìwé àlẹ̀ móde tí wọ́ n fi ṣe ìpolówó àwọn fíìmù, pàápàá jù lọ ní ikọ̀ fíìmù tí a mọ̀ sí Nollywood. Fún iṣẹ́ Digital Nollywood, a rí àwọn ohun èlò àfojúrí àti ìwé àlẹ̀ móde wọ̀ nyí gẹ́ gẹ́ bíi iṣẹ́ ọnà tí ó wúlò fún ìṣèwádìí iṣẹ́ ìtàn Nollywood ní ọ̀ nà tí ó yàtò. Ní oríṣiríṣi ọ̀ nà, iṣẹ́ yìí ń lo àwọn ìwé àlẹ̀ móde wọ̀ nyí láti ṣe àgbékalè ìtàn àwọn ohun ìkéde tí ó ṣe àmúlò àwọn nǹkan tí ó jé tiwantiwa. Ní ìtají sí bí àwọn ohun èlò àfojúrí àti ìwé àlẹ̀ móde wọ̀ nyí ti ṣe ń di àwátì, iṣẹ́ yìí ń ṣe àmúlò àwọn ìtẹ̀ síwájú tí ó pemọ́ ìmọ̀ ẹ̀ rọ láti wo àwọn ọ̀ nà míràn tí a lè gbà se iṣẹ́ ìwádìí ìtàn tàbí se àgbéyèwò àṣà àti ìṣe ní ilè Africa. Nípasẹ̀ àmúlò ohun àgbéjáde ayélujára, Digital Nollywood ní èrò láti di iṣẹ́ ìwádìí dígítà tí ó ń ṣe ìdásí àti ìtẹ́ pẹpẹ ìwé àlẹ̀ móde àwọn fíìmù Nollywood nípasẹ̀ àgbàjọ àwọn ìwé wọ̀ nyí ní orí pẹpẹ Omeka.   https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/134097
spellingShingle ‘Gbenga Adeoba
Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì”
Yoruba Studies Review
title Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì”
title_full Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì”
title_fullStr Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì”
title_full_unstemmed Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì”
title_short Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì”
title_sort agbeyewo digital nollywood o ro lati enu awon agba osere ati ogbontarigi
url https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/134097
work_keys_str_mv AT gbengaadeoba agbeyewodigitalnollywoodorolatienuawonagbaosereatiogbontarigi