Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló Lẹrù

Ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀ dá-èdè (linguistics) àti lítíréṣọ̀ ti wọnú ara wọn tí ó jẹ́ pé a fẹ́ rẹ̀ má le ya ọ̀ kan kúrò lára èkejì. Èròǹgbà iṣẹ́ yìí ni láti fi ìbáṣepọ̀ tí ó wà láàárin ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè àti lítíréṣọ hán. Láti ṣe èyí a yan ìwé-ìtàn –àròsọ Àjà Ló Lẹrù tí Òkédìjí kọ láàyò, a sì fi ẹ̀ka -ẹ̀kọ́ ìmọ̀ mọ...

Full description

Saved in:
Bibliographic Details
Main Authors: Folúkẹ Bọláńlé Adékẹ̀yè, Bọ́láńlé Elizabeth Arókoyọ̀
Format: Article
Language:English
Published: LibraryPress@UF 2021-12-01
Series:Yoruba Studies Review
Online Access:https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130089
Tags: Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
_version_ 1825205983600705536
author Folúkẹ Bọláńlé Adékẹ̀yè
Bọ́láńlé Elizabeth Arókoyọ̀
author_facet Folúkẹ Bọláńlé Adékẹ̀yè
Bọ́láńlé Elizabeth Arókoyọ̀
author_sort Folúkẹ Bọláńlé Adékẹ̀yè
collection DOAJ
description Ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀ dá-èdè (linguistics) àti lítíréṣọ̀ ti wọnú ara wọn tí ó jẹ́ pé a fẹ́ rẹ̀ má le ya ọ̀ kan kúrò lára èkejì. Èròǹgbà iṣẹ́ yìí ni láti fi ìbáṣepọ̀ tí ó wà láàárin ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè àti lítíréṣọ hán. Láti ṣe èyí a yan ìwé-ìtàn –àròsọ Àjà Ló Lẹrù tí Òkédìjí kọ láàyò, a sì fi ẹ̀ka -ẹ̀kọ́ ìmọ̀ mọfọ́lọ́jì tí í ṣe ẹ̀kọ́ ìṣẹ̀dá ọ̀rọ̀ nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè ṣe àyẹ̀wò ìlò ọ̀rọ̀-orúkọ (OR) aṣẹ̀dá nínú ìwé ìtàn-àròsọ yìí. Lára ọgbọ́n ìwádìí tí a lò ni pé a ka ìwé ìtàn àròsọ Àjà Ló Lẹrù dáadáa, a sì ṣe àfàyọ àwọn OR aṣẹ̀dá jáde nínú rẹ̀. Lẹ́yìn èyí ni a ṣe àkójọpọ̀ àti ìtúpalẹ̀ àwọn OR aṣẹ̀dá wọ̀nyí gẹ́gẹ́ bí ìlànà ìṣẹ̀dá wọn nínú ẹ̀kọ́ mọfọ́lọ́jì. A ṣe àyẹ̀wò àwọn iṣẹ́ tí ó jẹ mọ́ mọfọ́lọ́jì àti ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìsọwọ́lò-èdè àti lítíréṣọ̀ (stylistics) láti mú kí iṣẹ́ yìí kún ojú òsùnwọ̀n. Ní ìparí iṣẹ́ yìí, a rí i pé ipa tí ìlò àwọn OR aṣẹ̀ dá nínú ìwé ìtàn-àrosọ yìí kó kò kéré rárá. Àwọn OR aṣẹ̀dá yìí jẹ́ èròjà tí ó mú èdè ìwé náà kún, kí ó ki tí ó sì fi àwòrán àwọn ẹ̀dá ìtàn rẹ̀ hàn. Bí kò bá sí àwọn ẹ̀ka ìmọ̀ lítíréṣọ̀, ọ̀pọ̀ ọ̀rọ̀ aṣẹ̀dá pàápàá OR nínu ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá èdè ni kò ní wúlò bí a ṣe rí i nínú iṣẹ́ àpilẹ̀ kọ yíí. Lítíréṣọ̀ tún wá di orísun àfikún àká ọ̀ rọ̀ nínú ìmọ̀ ẹ̀ dá-èdè.
format Article
id doaj-art-1b93e45804464a20b75377ae2021aca0
institution Kabale University
issn 2473-4713
2578-692X
language English
publishDate 2021-12-01
publisher LibraryPress@UF
record_format Article
series Yoruba Studies Review
spelling doaj-art-1b93e45804464a20b75377ae2021aca02025-02-07T13:45:06ZengLibraryPress@UFYoruba Studies Review2473-47132578-692X2021-12-0161Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló LẹrùFolúkẹ Bọláńlé Adékẹ̀yè 0Bọ́láńlé Elizabeth Arókoyọ̀ 1University of ÌlọrinUniversity of Ìlọrin Ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀ dá-èdè (linguistics) àti lítíréṣọ̀ ti wọnú ara wọn tí ó jẹ́ pé a fẹ́ rẹ̀ má le ya ọ̀ kan kúrò lára èkejì. Èròǹgbà iṣẹ́ yìí ni láti fi ìbáṣepọ̀ tí ó wà láàárin ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè àti lítíréṣọ hán. Láti ṣe èyí a yan ìwé-ìtàn –àròsọ Àjà Ló Lẹrù tí Òkédìjí kọ láàyò, a sì fi ẹ̀ka -ẹ̀kọ́ ìmọ̀ mọfọ́lọ́jì tí í ṣe ẹ̀kọ́ ìṣẹ̀dá ọ̀rọ̀ nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè ṣe àyẹ̀wò ìlò ọ̀rọ̀-orúkọ (OR) aṣẹ̀dá nínú ìwé ìtàn-àròsọ yìí. Lára ọgbọ́n ìwádìí tí a lò ni pé a ka ìwé ìtàn àròsọ Àjà Ló Lẹrù dáadáa, a sì ṣe àfàyọ àwọn OR aṣẹ̀dá jáde nínú rẹ̀. Lẹ́yìn èyí ni a ṣe àkójọpọ̀ àti ìtúpalẹ̀ àwọn OR aṣẹ̀dá wọ̀nyí gẹ́gẹ́ bí ìlànà ìṣẹ̀dá wọn nínú ẹ̀kọ́ mọfọ́lọ́jì. A ṣe àyẹ̀wò àwọn iṣẹ́ tí ó jẹ mọ́ mọfọ́lọ́jì àti ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìsọwọ́lò-èdè àti lítíréṣọ̀ (stylistics) láti mú kí iṣẹ́ yìí kún ojú òsùnwọ̀n. Ní ìparí iṣẹ́ yìí, a rí i pé ipa tí ìlò àwọn OR aṣẹ̀ dá nínú ìwé ìtàn-àrosọ yìí kó kò kéré rárá. Àwọn OR aṣẹ̀dá yìí jẹ́ èròjà tí ó mú èdè ìwé náà kún, kí ó ki tí ó sì fi àwòrán àwọn ẹ̀dá ìtàn rẹ̀ hàn. Bí kò bá sí àwọn ẹ̀ka ìmọ̀ lítíréṣọ̀, ọ̀pọ̀ ọ̀rọ̀ aṣẹ̀dá pàápàá OR nínu ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá èdè ni kò ní wúlò bí a ṣe rí i nínú iṣẹ́ àpilẹ̀ kọ yíí. Lítíréṣọ̀ tún wá di orísun àfikún àká ọ̀ rọ̀ nínú ìmọ̀ ẹ̀ dá-èdè. https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130089
spellingShingle Folúkẹ Bọláńlé Adékẹ̀yè
Bọ́láńlé Elizabeth Arókoyọ̀
Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló Lẹrù
Yoruba Studies Review
title Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló Lẹrù
title_full Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló Lẹrù
title_fullStr Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló Lẹrù
title_full_unstemmed Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló Lẹrù
title_short Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló Lẹrù
title_sort aye ̀wo ilo apola oruko aseda ninu iwe itanaroso aja lo leru
url https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130089
work_keys_str_mv AT folukebolanleadekeye ayewoiloapolaorukoasedaninuiweitanarosoajaloleru
AT bolanleelizabetharokoyo ayewoiloapolaorukoasedaninuiweitanarosoajaloleru