Àìgbọ́ àti àìlèsọ èdè Yorùbá àti àbáyọ fún àwọn ọmọ Yorùbá ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
Ohun ti o je mi logun ninu apileko yii ni bi ogooro awon omo bibi ile Yoruba ni ile Amerika ko se le so tabi gbo ede Yoruba. Akiyesi mi ni pe, oro naa dabi oro amukun-un ti eru re ti wo lati ile ni. Mo salaye wi pe ainifee ede Yoruba lokan wa lara isoro ti o n koju opolopo awon omo bibi Yoruba ti w...
Saved in:
Main Author: | |
---|---|
Format: | Article |
Language: | English |
Published: |
LibraryPress@UF
2021-12-01
|
Series: | Yoruba Studies Review |
Online Access: | https://ojs.test.flvc.org/ysr/article/view/130147 |
Tags: |
Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
|